Heberu 12:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa lépa alaafia lọ́dọ̀ gbogbo eniyan pẹlu ìwà mímọ́. Láìṣe bẹ́ẹ̀ kò sí ẹni tí yóo rí Oluwa.

Heberu 12

Heberu 12:13-23