Heberu 11:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa igbagbọ ni Isaaki fi súre fún Jakọbu ati Esau tí ó sì sọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ sí wọn.

Heberu 11

Heberu 11:15-23