Heberu 10:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbẹ̀ ni ó wà tí ó ń retí ìgbà tí gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ yóo di àpótí-ìtìsẹ̀ rẹ̀.

Heberu 10

Heberu 10:6-20