Heberu 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí ó mú àkọ́bí rẹ̀ wọ inú ayé, ohun tí ó sọ ni pé,“Kí gbogbo àwọn angẹliỌlọrun foríbalẹ̀ fún un.”

Heberu 1

Heberu 1:1-11