Heberu 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Èwo ninu àwọn angẹli ni ó fi ìgbà kan sọ fún pé,“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mi,títí n óo fi ṣe àwọn ọ̀tá rẹ ní àpótí ìtìsẹ̀ rẹ?”

Heberu 1

Heberu 1:4-14