Hagai 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ni Hagai, òjíṣẹ́ OLUWA, bá jẹ́ iṣẹ́ tí OLUWA rán an sí àwọn eniyan náà pé òun OLUWA ní òun wà pẹlu wọn.

Hagai 1

Hagai 1:9-15