Habakuku 3:18-19 BIBELI MIMỌ (BM)

18. sibẹsibẹ, n óo yọ̀ ninu OLUWA,n óo yọ̀ ninu Ọlọrun Olùgbàlà mi.

19. Ọlọrun, OLUWA, ni agbára mi;Ó mú kí ẹsẹ̀ mi yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín,ó mú mi rìn lórí àwọn òkè gíga.(Sí ọ̀gá akọrin; pẹlu àwọn ohun èlò orin olókùn.)

Habakuku 3