Habakuku 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ àwọn onígbèsè rẹ kò ní dìde sí ọ lójijì, kí àwọn tí wọn yóo dẹ́rùbà ọ́ sì jí dìde, kí o wá di ìkógun fún wọn?

Habakuku 2

Habakuku 2:1-13