Habakuku 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ẹni tí ọkàn rẹ̀ kò ṣe déédéé ninu OLUWA yóo ṣègbé; ṣugbọn olódodo yóo wà láàyè nípa igbagbọ.”

Habakuku 2

Habakuku 2:1-8