Habakuku 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti kó ìtìjú bá ilé rẹ nítorí ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè tí o parun; ìwọ náà ti wá pàdánù ẹ̀mí rẹ.

Habakuku 2

Habakuku 2:9-17