Habakuku 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo dúró sí ibìkan lórí ilé-ìṣọ́, n óo máa wòran. N óo dúró, n óo máa retí ohun tí yóo sọ fún mi, ati irú èsì tí èmi náà óo fún un.

Habakuku 2

Habakuku 2:1-7