Galatia 6:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí alaafia ati àánú Ọlọrun kí ó wà pẹlu gbogbo àwọn tí ó bá ń gbé ìgbé-ayé wọn nípa ìlànà yìí, ati pẹlu àwọn eniyan Ọlọrun.

Galatia 6

Galatia 6:6-17