Galatia 4:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ kì í ṣe ẹrú mọ́ bíkòṣe ọmọ. Bí ẹ bá wá jẹ́ ọmọ, ẹ di ajogún nípasẹ̀ iṣẹ́ Ọlọrun.

Galatia 4

Galatia 4:1-12