Galatia 4:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ gan-an ni ó rí pẹlu wa. Nígbà tí a jẹ́ ọmọde, a jẹ́ ẹrú àwọn oríṣìíríṣìí ẹ̀mí tí a kò fojú rí.

Galatia 4

Galatia 4:1-5