Filipi 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò sọ èyí nítorí mo ṣe aláìní, nítorí mo ti kọ́ láti máa ní ìtẹ́lọ́rùn ní ipòkípò tí mo bá wà.

Filipi 4

Filipi 4:1-13