Filipi 3:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ti ìtara ninu ẹ̀sìn, mo ṣe inúnibíni sí ìjọ Kristi. Ní ti òdodo nípa iṣẹ́ Òfin, n kò kùnà níbìkan.

Filipi 3

Filipi 3:3-13