Filipi 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwa gan-an ni ọ̀kọlà, àwa tí à ń sin Ọlọrun nípa Ẹ̀mí, tí à ń ṣògo ninu Kristi Jesu, tí a kò gbára lé nǹkan ti ara,

Filipi 3

Filipi 3:1-6