Filipi 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìparun ni ìgbẹ̀yìn wọn. Ikùn wọn ni ọlọrun wọn. Ohun ìtìjú ni wọ́n fi ń ṣe ìgbéraga. Afẹ́-ayé ni wọ́n gbé lékàn.

Filipi 3

Filipi 3:18-20