Filipi 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ará, gbogbo yín ẹ máa fara wé mi, kí ẹ máa ṣàkíyèsí àwọn tí ń hùwà gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ tí a ti jẹ́ fun yín.

Filipi 3

Filipi 3:14-21