Filipi 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ní wéréwéré yìí ni mò ń rán an bọ̀ kí ẹ lè tún rí i, kí inú yín lè dùn, kí ọkàn tèmi náà sì lè balẹ̀.

Filipi 2

Filipi 2:19-30