Filipi 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí a bá fi mí ṣe ohun ìrúbọ ati ohun èèlò ninu ìsìn nítorí igbagbọ yín, ó dùn mọ́ mi, n óo sì máa yọ̀ pẹlu gbogbo yín.

Filipi 2

Filipi 2:10-19