Filipi 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dá mi lójú pé ẹni tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rere ninu yín yóo ṣe é dé òpin títí di ọjọ́ tí Kristi Jesu yóo dé.

Filipi 1

Filipi 1:1-15