Filipi 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo bá wà láàyè ninu ẹran-ara, iṣẹ́ tí ó lérè ni ó jẹ́ fún mi. N kò tilẹ̀ mọ èyí tí ǹ bá yàn.

Filipi 1

Filipi 1:13-23