Filipi 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹlòmíràn ń waasu Kristi nítorí owú ati nítorí pé wọ́n fẹ́ràn asọ̀. Àwọn ẹlòmíràn sì wà tí wọn ń waasu Kristi pẹlu inú rere.

Filipi 1

Filipi 1:11-18