Filipi 1:10 BIBELI MIMỌ (BM)

kí ẹ lè mọ àwọn ohun tí ó dára jùlọ. Kí ẹ lè jẹ́ aláìlábùkù, kí ẹ sì wà láìsí ohun ìkùnà kan ní ọjọ́ tí Kristi bá dé.

Filipi 1

Filipi 1:4-14