Filipi 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi Paulu ati Timoti, àwa iranṣẹ Kristi Jesu.À ń kọ ìwé yìí sí gbogbo àwọn eniyan Ọlọrun tí ó wà ní ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu, tí wọ́n wà ní Filipi pẹlu gbogbo àwọn alabojuto ati àwọn olùrànlọ́wọ́ wọn.

Filipi 1

Filipi 1:1-6