Filemoni 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Adura mi ni pé kí àjọṣepọ̀ tàwa-tìrẹ ninu igbagbọ lè ṣiṣẹ́, láti mú kí òye rẹ pọ̀ sí i nípa gbogbo ohun rere tí a ní ninu Kristi.

Filemoni 1

Filemoni 1:5-12