Filemoni 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ku nǹkankan: Tọ́jú ààyè sílẹ̀ dè mí, nítorí mo ní ìrètí pé, nípa adura yín, Ọlọrun yóo jẹ́ kí wọ́n dá mi sílẹ̀ fun yín.

Filemoni 1

Filemoni 1:17-23