Ẹsita 9:6-9 BIBELI MIMỌ (BM)

6. Ní ìlú Susa nìkan, àwọn Juu pa ẹẹdẹgbẹta (500) eniyan.

7. Wọ́n sì pa Paṣandata, Dalifoni, Asipata,

8. Porata, Adalia, Aridata,

9. Pamaṣita, Arisai, Aridai ati Faisata.

Ẹsita 9