Ẹsita 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn Juu fi idà pa àwọn ọ̀tá wọn, wọ́n pa wọ́n run. Ohun tí ó wù wọ́n ni wọ́n ṣe sí àwọn tí wọ́n kórìíra wọn.

Ẹsita 9

Ẹsita 9:2-13