Ẹsita 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn olórí àwọn agbègbè, àwọn baálẹ̀, àwọn gomina ati àwọn aláṣẹ ọba ran àwọn Juu lọ́wọ́, nítorí pé ẹ̀rù Modekai ń bà wọ́n.

Ẹsita 9

Ẹsita 9:1-8