Ẹsita 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mẹ́wẹ̀ẹ̀wá jẹ́ ọmọ Hamani, ọmọ Hamedata, ọ̀tá àwọn Juu, ṣugbọn wọn kò fọwọ́ kan àwọn ẹrù wọn.

Ẹsita 9

Ẹsita 9:5-13