Ẹsita 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasu-erusi ọba dá Ẹsita Ayaba ati Modekai Juu lóhùn pé, “Mo ti so Hamani kọ́ sórí igi, nítorí ète tí ó pa lórí àwọn Juu, mo sì ti fún Ẹsita ní ilé rẹ̀.

Ẹsita 8

Ẹsita 8:1-11