Ẹsita 8:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba mú òrùka tí ó gbà lọ́wọ́ Hamani, ó fi bọ Modekai lọ́wọ́. Ẹsita sì fi Modekai ṣe olórí ilé Hamani.

Ẹsita 8

Ẹsita 8:1-6