Ẹsita 8:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹlu àṣẹ ọba, àwọn iranṣẹ gun àwọn ẹṣin ọba, wọ́n sì yára lọ. Wọ́n pa àṣẹ náà ní Susa tíí ṣe olú-ìlú.

Ẹsita 8

Ẹsita 8:12-17