Ẹsita 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsita ayaba dáhùn, ó ní, “Kabiyesi, bí mo bá rí ojurere rẹ, bí ó bá sì wù ọ́, dá ẹ̀mí mi ati ti àwọn eniyan mi sí.

Ẹsita 7

Ẹsita 7:2-9