Ẹsita 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá ní kí wọ́n lọ gbé Hamani kọ́ sí orí rẹ̀. Wọ́n bá gbé Hamani kọ́ sí orí igi tí ó ti rì mọ́lẹ̀ fún Modekai, nígbà náà ni inú ọba tó rọ̀.

Ẹsita 7

Ẹsita 7:9-10