Ẹsita 6:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn iranṣẹ ọba dá a lóhùn pé, “Hamani wà níbẹ̀ tí ó ń duro ní àgbàlá.” Ọba sì wí pé, “Ẹ jẹ́ kí ó wọlé.”

Ẹsita 6

Ẹsita 6:3-8