Ẹsita 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Modekai pada sí ẹnu ọ̀nà ààfin, ṣugbọn Hamani sáré pada lọ sí ilé rẹ̀ pẹlu ìbànújẹ́, ó sì bo orí rẹ̀.

Ẹsita 6

Ẹsita 6:2-14