Ẹsita 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n níláti sọ ohun tí ó wà ninu ìwé náà di òfin ní gbogbo ìgbèríko, kí wọ́n sì sọ fún gbogbo eniyan, kí wọ́n lè múra sílẹ̀ de ọjọ́ náà.

Ẹsita 3

Ẹsita 3:7-15