Ẹsita 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá se àsè ńlá fún àwọn olóyè ati àwọn iranṣẹ rẹ̀ nítorí Ẹsita. Ó fún gbogbo eniyan ní ìsinmi, ó sì fún wọn ní ọpọlọpọ ẹ̀bùn.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:12-23