Ẹsita 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n mú Ẹsita lọ sọ́dọ̀ ọba Ahasu-erusi ní ààfin rẹ̀ ní oṣù Tebeti, tíí ṣe oṣù kẹwaa, ní ọdún keje ìjọba rẹ̀.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:12-20