Ẹsita 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, tí ibinu ọba rọlẹ̀, ó ranti ohun tí Faṣiti ṣe, ati àwọn àṣẹ tí òun pa nípa rẹ̀.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:1-5