Ẹsita 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ọba se àsè ní àgbàlá ààfin fún ọjọ́ meje, fún gbogbo àwọn tí wọ́n wà ní Susa, àtàwọn talaka, àtàwọn eniyan ńláńlá.

Ẹsita 1

Ẹsita 1:1-7