Ẹsita 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí a bá kéde òfin yìí jákèjádò agbègbè rẹ, àwọn obinrin yóo máa bu ọlá fún àwọn ọkọ wọn; ọkọ wọn kì báà jẹ́ talaka tabi olówó.”

Ẹsita 1

Ẹsita 1:13-22