Ẹsita 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

pé kí wọ́n lọ mú Ayaba Faṣiti wá siwaju òun, pẹlu adé lórí rẹ̀, láti fi ẹwà rẹ̀ han gbogbo àwọn eniyan ati àwọn olórí, nítorí pé ó jẹ́ arẹwà obinrin.

Ẹsita 1

Ẹsita 1:4-18