Ẹsita 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò tí Ahasu-erusi jọba ní ilẹ̀ Pasia, ìjọba rẹ̀ tàn dé agbègbè mẹtadinlaadoje (127), láti India títí dé Kuṣi ní ilẹ̀ Etiopia.

Ẹsita 1

Ẹsita 1:1-2