Ẹsira 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ọmọ Joabu, Ọbadaya, ọmọ Jehieli, ni olórí;orúkọ igba eniyan ó lé mejidinlogun (218) ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:7-17