Ẹsira 8:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ọmọ Pahati Moabu, Eliehoenai, ọmọ Serahaya, ni olórí;orúkọ igba (200) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:1-7