Ẹsira 8:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn alufaa ati àwọn ọmọ Lefi gba fadaka, wúrà ati àwọn ohun èlò náà, wọ́n kó wọn wá sinu ilé Ọlọrun wa ní Jerusalẹmu.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:24-36